ÌTÀN ÌGBÉSÍ-AYÉ ÀWỌN OLÓRIN YORÙBÁ (APÁ KÍNNÍ)

Oláyíwolá Fatai Olágunjú

tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Fatai Rolling Dollar (22 July 1927-12 June 2013)jẹ́ Olórin jùjú ọmọ bíbí orílè-èdè Nàìjíríà.

Akọ̀wé akọrin sílè ni ó sì tún má ń lu àwọn èròjà orin onírúurú gẹ́gẹ́ bí BBC tí ṣe sàkàwẹ́ rẹ.

Gégé bí Olórin tí wọn ṣe àyésí re káàkiri orile-ede.

Olayiwola Fatai Olágunjú ti a mọ̀ sí Fatai Rolling Dollar tótó omi ayé wo ni ọjọ́ kejì lè lógún oṣù keje ọdún 1927, Ó sì kú ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹfà ọdún 2013.O je olorin jùjú ọmọ bíbí orílè-èdè Nàìjíríà. Ó bere isẹ́ orin rẹ ni odun 1953.,ati pe o ti ko awon ọ̀pọ̀lọpọ̀ Olórin bí Ebenezer Obey àti olóògbé Orlando Oworh. Ó di ìlú m̀ońká pẹ̀lú títa gira rẹ tí ó yá lára oto. Àwọn orin Rolling Dollar tí ó gbajugbaja gbeyin ni ” won kere si Number wa”.

Ó kú ikú Àlàáfíà láti ojú oru rẹ. Wọn sì sìn ín sí ikorodu ni Ipinle Eko. Ó jé Olórin ilé Nàìjíríà tí ó ti pé jùlo.

Orlando Oworh

A bí Stephen Oladipupo olaore Owomeyela:(14/2/1932-4/11/2008) jẹ́ ọmọ orile-ede Nàìjíríà tí ó kọrin tí o si je olori egbe àwọn akọrin tí ó ṣe láti ilé Yorùbá.

Stephen Oladipupo Olaore Owomeyela tí a padà mo sì Oloye, omowe Orlando Oworh wá sí ayé ni ilu Osogbo, Nàìjíríà ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1932 sínú ìdílé Oloye Atanneye Owomeyela àti arábìnrin Christiana Morenike Owomeyela. Ifon ni ìpínlè Ondo ni bàbá rè tí dàgbà, tí ìyà rẹ na si je omo bibi ìlú ọ̀wọ̀. Baba rẹ jẹ kanlẹ́-kanlẹ́ tí ó sì tún má ń kó orin lèkookan ni ilu Osogbo. Gégé bí ọmọ ọkùnrin,Oworhse ìṣe kanlẹ́ kanlẹ́ títí di ọdún 1958, ní ìgbà tí wọn gba sínú egbe osere orí ìtàgé, ọmọ orile-ede Nàìjíríà kan Kola Ogunmola láti máa lu ìlù àti kò orin. Oworhse lọ dá egbe akọrin Orlando Oworhse àti àwọn elegbe rẹ sílè ni odun 1960, eyi ti o si sọ irin ajo ogójì ọdún nìdí ìṣe orin rẹ di asiwaju nìdí ìṣe orin pelu egbe orin bí omiman èyí tí ó padà di egbe odò kenneries àti kenneries ẹ adúláwò tí àgbáyé. Oworh je gbajugbaja ni ile Nàìjíríà, kò dá títí di asiko orin ìgbàlódé jùjú àti fuji. Ó ní àwo orin tó lè ní márùn-ún dín-ogota gege bí àṣeyọrí rẹ. Orlando Oworh kú ní ọjọ́ kẹrin, Osu kọkànlá ọdún 2008. Ó wọ kaa ilé lọ ní agege ni Ipinle Eko, Nàìjíríà. ìṣe orin leyin ilé ìwé gírámà rẹ ni ile eko Rẹmo ni sagamu ipinle ogun. Bí ó ti lè jẹ pe o wole láti kó nípa ìṣe ona rẹ ni ile eko giga gbogbo nise tí ìjọba ipinle Abeokuta, ṣùgbọ́n ìṣe orin kiko rẹ lọ dúró sí àárín gbùngbùn. Ayuba gbé àwo orin rẹ àkókò tí ó pè ní ibère (beginning) jáde ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún, pelu èyí ó tètè dìde gidi gidi nínú àwọn tí wón kó orin fuji.

Àwọn orin tí ó ti kọ.
Àwọn àwo orin tí Omowe Orlando Owoh.

  • Aiye nyi lo Medley
  • Ajanaku Daraba
  • Apartheid
  • Asotito Aye
  • Awa de
  • Ayo mi sese bere
  • Cain ati Abel
  • Easter special
  • E ku iroju
  • E Get As E Be
  • Emi wa wa lowo re
  • Experience
  • Ganja I
  • Ganja II
  • Ibaje eniyan
  • Igba aye Noah
  • Ire loni
  • I say No
  • Iwa l’Oluwa Now
  • Iyawo Olele
  • Jeka sise
  • Kangaroo
  • Kennery de ijo ya
  • Kose mani
  • Late Dele Giwa
  • Logba Logba
  • Ma wo mi roro
  • Message
  • Mo juba agba
  • Money 4 hand back 4 ground
  • Oriki Ojo
  • Orin titun
  • Thanksgiving
  • Which is which

Àwọn àwo orin àdákọ rẹ ni (A kò tò wọ́n ní ṣíṣẹ̀-n-tẹ̀lé):

  • Brother ye se
  • Day by day
  • Diana
  • Ebe mo be ori mi
  • Zo Muje
  • Egi nado
  • Elese (sinner)
  • Fiba fun Eledumare
  • Ma pa mi l’oruko da
  • Ma sika Ma doro
  • Modupe Medley
  • Oju ni face
  • Okan mi yin Oba orun
  • Olorun Oba da wa lohun Medley
  • Oro loko laya
  • Rex Lawson
  • Wa ba mi jo
  • Yabomisa sawale
  • You be my lover

Ayinde Bakare(1012-1972)

A bí Saibu Ayinde Bakare ni odun 1912 sí Òkeesúnà Láfíàjí ní agbègbè Èkó. Jagunjagun ni bàbá rẹ̀, Pa Bakare, jẹ́ ọmọ agbolé e Ajikobi ni Ilorin, ipinle kwara. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀ ní St.Mathiaw catholic school, Lafiaji.Lẹ́yìn ìgbà náà, ó kọ́ iṣẹ́ olùkàn ọkọ̀-ojúomi pẹ̀lú àwọn old marine department ní eko. Ó bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò iṣẹ́ orin rẹ̀ lẹ́hìn tí ó wo eré àwọn ẹgbẹ́ olórin níbi ìgbéyàwó láti ọwọ́ ọ Tunde king. Bakare tún ṣeré fún olórin juju kan, Alabi labilu. Ọ̀kan lára àwọn àwo juju rẹ̀ ni Layika sapara, Orin iyin tí ó kọ fún ọmọbìnrin Oguntola Sapara, Lára orin inú àwo yìí ni Ajibabi.

Bakare dá ẹgbẹ́ orin kan sílẹ̀ tí wọ́n pè ni Meranda lẹ́hìn fíìmù Miranda Ẹ̀gbẹ́ yìí bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọmọ ẹgbẹ́ mẹ́rin, ó di ọmọ ẹgbẹ́ mẹ́jọ ní odún 1959. Ó jẹ́ òní juju àkọ́kọ́ tí yóò lo AMPLIFIED GUITAR, ní 1949, idà sílẹ̀ bakare mú ayípadà wo orin juju ni Nàìjíríà lẹ́hìn Ogun àgbáyé Kejì. Ó jẹ́ gbajúmọ̀ àti olókìkí káàkiri ilé Yorùbá, pàápàá ní eko àti ìbàdàn ní 1950 àti 1960, èyí fún un ní ìnagijẹ̀ “Mr Juju”. Ó ṣe àbẹ̀wò sí Britain ní 1957. Àwọn àwo rẹ̀ ni;1968 LP Live the Highlife (Melodisc MLPAS 12-140). Tribute to the late J. K. Randle / Eko Akete (Lagos Akete) / Adura Fun Awon Aboyun (Prayer for the Pregnant Women) / Ibikunle Alakija /Iwalewa (Your Manner is Your Beauty) / Ore Otito O Si (There’s no true friend) / Mo b’eru Aiye (I fear the humanity) / Ile Aiye Ile Asan (Life is vanity upon vanity) / Agboola Odunekan / Olabisi Arobieke /Akambi Balogun.

  • MLP 12-134 Great African Highlife Music Vol 2 Various Artists – includes
    Ayinde Bakare – Iwa Lewa/ Adura Fun Awon Aboyun / Se Botimo / The Late J.K. Randle
  • 1406 The Late J.K. Randle/Ibikunle Alakija
  • 1431 Iwa Lewa/J.O. Majekodunmi
  • 1446 Se Botimo/S. Ola Shogbola
  • 1465 Tafawa Balewa/Public Interest
  • 1467 Adura Fun Awon Aboyun/Fagbayi Contractor
  • 1492 Kamila Mustapha/Asewo Erori
  • 1588 Eko Dara Eko Ndun / Rt. Hon. Dr. Azikiwe

Ó kú ní ọdún 1972, ìdí ikú rẹ̀ kò sì hànde lẹ́yìn tí ó parí eré ní ibi ayẹyẹ ìgbéyàwó kàn ní ìpínlè èkó

Àwọn elégbè rẹ síwọ́ eré lẹ́yìn tí wọn pé Bakare sẹ́yìn agbo. Kò padà dé mọ́, tí wọ́n sì rí òkú rẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ kẹta tí ó ti wú sórí omi òkun ní Èkó.

Sunday Adeniyi Adegeye MFR

Ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1946 ni a bí Sunday Adeniyi Adegeye tí a mọ̀ sí King Sunny Ade, olórin Juju Nàìjíríà tí ó tún jẹ́ akọrin sílẹ̀ àti ẹni tí ó mọ èlò orin dáradára ní ìlu oṣogbo sí ìdílè ọba láti ìlú Ondo àti Akurẹ, èyí sọ ọ́ di ọmọba fún àwọn ọmọ Yorùbá. Ó jẹ́ olórin African pop tó ní àṣeyọrí ìlú òkèrè tí a sì ń pè ní gbajúmọ̀ olórin ìgbà gbogbo.

Sunny Ade dá ẹgbẹ́ elégbè rẹ̀ sílẹ̀ ní 1967, tí a mọ̀ sí African Beats. Lẹ́hìn tí ó ní àṣeyọrí orílẹ̀-èdè ní Nàìjíría ní 1970 àti ìdásílẹ̀ record label, Sunny Ade tọwọ́ pẹ̀lú Island Record ní 1982 àti àṣeyọrí ní ìlú òkèrè pẹ̀lú àwọn àwo orin juju music(1982) àti synchro system (1983); fún un ní ore-ọ̀fẹ́ sí àmi ẹ̀yẹ Grammy.

Sunny Ade sìn bíi Alága ẹgbẹ́ Musical copyright society of Nigeria kí ó tó gba àṣẹ ìjọba,Lẹ́hìn náà ni wọ́n gẹ́gẹ́ bíi ààrẹ ẹgbẹ́ nítorí amòye olórí tí ó ní nínú ẹgbẹ́ náà. Sunny Ade kúrò ni ilé-èkó girama ní ìlú Ondo pẹ̀lú ète pé òun lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìlú eko. Ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Moses olaiva’s Federal Rhythm Dandies, ẹgbé alálùjó ó sì Kúrò nínú ẹgbẹ́ náà láti lò dá ti ẹ̀ sílẹ̀, The Green spots, ní 1967. Olórin Juju nì, Tunde Nightingale ní ipa nínú ayé Sunny Ade, ó yá díẹ̀ nínú ìṣọwọ́ seré  “so wa mbè”.Ó dá King Sunny Ade foundation kalẹ̀, ẹgbẹ́ wà fún, ibi ìṣèré tíátà, ibi ìgbohùn orin sílẹ̀ (state-of-the-art) àti ilé fún àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ olórin. Ó ṣe àbẹ̀wò sí àwọn olùkọ́ ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo,Ile-Ife, a recipient of the order of the federal republic.

Ó jẹ́ ọmọ Nàìjíría àkọ́kọ́ tí a yàn fún àmì-ẹ̀yé Grammys. Gẹ́gẹ́ bíi olórin pẹ̀lú ọwọ́ àrà àti ijó, ó ti gba òpòlopò àmì-ẹ̀yẹ ní Nàìjíría ati ní òkè-òkun. Ní 1980, Sunny Ade ṣiṣẹ́ pẹ̀lú fíìmù àgbéléwò Hollywood. Orin rẹ̀ jẹyọ nínu fíìmù Breathless 1983, Ẹ̀fẹ̀ 1986 (one more Saturday night), ó farahàn nínu àwọn fíìmù Nollywood díẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdun 2000. Ó gba oríṣiríṣi àmì-ẹ̀yẹ nígbà ayé

Ebenezer Remilekun Aremu Olasupo Obey-Fabiyi MFR

A bí Ebenezer Remilekun Aremu olasupo Obey-fabiyi ni ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin ọdún 1942 sí ìdílé Egba -Yoruba. Obey, tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Ebenezer Remilekun Aremu Olasupo Fabiyi, jẹ ọmọ bíbí ìlú idogo ní ìpínlẹ̀ Ogun Nàìjíríà ti Ẹ̀gba-yoruba. Ó ẹ̀yà Owu ti Ẹgba. Ebenezer Obey bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò iṣẹ́ orin rẹ̀ ní àárín 1950 lẹ́hìn tí ó dé Eko, lẹ́hìn tí ó gba ìdarí nínu ẹgbẹ́ Fatai Rolling-dollar, ó dá ẹgbẹ́ orin sílẹ̀ ní 1964 tí wọ́n pè ní The International Brothers, wọ́n kọrin àlùjó-juju. Ẹ̀gbẹ́ náà yípadà sí Inter-Reformer in ìbẹ̀rẹ̀ 1970, pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwo juju lóri the West Africa Decca musical label.

Obey, tún jẹ́ olórintí ó máa ń lo ìmísì kìrìsítíẹ́nì nínú àwọn orin ajẹmọ́-ẹ̀sìn rẹ̀ gbogbo. Láti ọdún 1990 ni ó ti fẹ̀yìntì padà sí inú orin ajíhìnrere. Obey fẹ́ Juliana Olaide Olufade ní ọdún 1963. Tí wọn sì mọ orúkọ ìyàwó rẹ̀ sí Arábìnrin Ajíhìnrere Juliana Obey-Fabiyi.

Àwọn orin tí ó ti kọ.            

  • 1964 Ewa Wo Ohun Ojuri
  • 1965 Aiye Gba Jeje b/w Ifelodun*Gari Ti Won b/w Orin Adura
  • 1966 Awolowo Babawa Tide b/w Oluwa Niagbara Emi Mi*Palongo b/w Teti Ko Gboro Kan*Oro Miko Lenso b/w Orin Ajinde*Late Justice Olumide Omololu b/w Iyawo Ti Mo Ko Fe
  • 1967 Olomi Gbo Temi b/w Maria Odeku*To Keep Nigeria One b/w Awa Sope Odun Titun*Edumare Lon Pese b/w Omo Olomo*Ope Fun Oluwa b/w Paulina
  • 1968 Ore Mi E Si Pelepele b/w Ajo Ni Mo wa*Ijebu L’ade b/w Lati Owolabi*Col. Ben Adekunle b/w Ori Bayemi*Lolade Wilkey b/w Adetunji Adeyi*Gbe Bemi Oluwa b/w Olowo Laiye Mo
  • 1969 Ode To Nso Eledumare b/w Pegan Pegan*Sanu-olu b/w K’Oluwa So Pade Wa*London Lawa Yi b/w Oro Seniwo*Isokan Nigeria / etc.*Eni Mayo Ayo / etc1969/1970*Emi Yio Gbe Oluwa Ga b/w Ise Teni
  • 1970 Lawyer Adewuyi*Ala Taja Bala b/w Ohun Toluwa Ose*Ogun Pari / etc.*In London*On The Town
  • 1971 Ija Pari (Part One) b/w Ija Pari (Part Two)*Esa Ma Miliki b/w Awon Alhaji*Face to Face b/w Late Rex Lawson*Oro Nipa Lace b/w Yaro Malaika
  • 1972 Late Oba Gbadelo II*Board Members*Vol.4: Aiye Wa A Toro*In London Vol. 3*Odun Keresimesi
  • 1973 And His Miliki Sound*The Horse, The Man and His Son*E Je Ka Gbo T’Oluwa*Adeventure of Mr. Music*Mo Tun Gbe De
  • 1974 Inter-Reformers A Tunde*Eko Ila*Around the World*Iwalka Ko Pe
  • 1975 Mukulu Muke Maa Jo*Ota Mi Dehin Lehin Mi*Alo Mi Alo*Edumare Dari Jiwon
  • 1976 Late Great Murtara Murtala Ramat Muhammed*Operation Feed The Nation
  • 1977 Eda To Mose Okunkun*Immortal Sings for Travellers*Adam and Eve
  • 1978 Igba Owuro Lawa*Oluwa Ni Olusa Aguntan Mi*No Place Be Like My Country Nigeria
  • 1979 In the Sixties Vol.1*In the Sixties Vol.2*Igba Laiye*Sky*E Wa Kiye Soro Mi*Omo Mi Gbo Temi
  • 1980 Leave Everything to God*Current Affairs*Sound of the Moment*Eyi Yato
  • 1981 Joy of Salvation*What God Has Joined Together
  • 1982 Celebration*Austerity*Precious Gift
  • 1983 Ambition*Singing for the People*Greatest Hits Vol. 3*Je Ka Jo*Thank You (Ose)
  • 1984 The Only Condition to Save Nigeria*Solution*Peace1985*Security*My Vision
  • 1986 Gbeja Mi Eledumare*Satisfaction*Providence
  • 1987 Aimasiko*Immortality*Victory*Patience
  • 1988 Determination*Vanity
  • 1989 Formula 0-1-0*Get Yer Jujus Out
  • 1990 Count Your Blessing*On the Rock
  • 1991 Womanhood
  • 1993 Good News
  • 1994 I Am a Winner*Walking Over.
  • 1995 The Legend
  • 1999 Millennial Blessings
  • 2000 Promised Land
  • 2002 Ase Oluwa

Bisade Ologunde

Bisade Ologunde Bisade Ologunde jẹ́ akọrin afrobeat Nàìjíríà, olórin àti ẹni tí ó máa ń kọ orin sílẹ̀, Tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Lágbájá, tí  ó máa bojú fún ìdánimọ̀ rẹ̀ ni a bí sí ìlú Eko ní 1960. Ologunde gba orúkọ rẹ̀ Lágbájá ( tí ó túnmọ̀ sí “jane Doe” tàbí “John Doe” Ẹni ti orúkọ̀ bá ti ìlú òkèrè mu pẹ̀lú Yorùbá) ó  bro iṣẹ́ ẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ ní ọdún 90. Orúkọ rẹ̀ hàn nínú yíyan   aṣọ ìtàgé, aṣọ tí a gé pẹ̀lú ìbòjú rọ́bà fún ìdánimọ̀ rẹ̀ tí ó túnmọ̀ síi (Ọkùnrin Lásán) láti pa àṣà Yorùbá mọ́. Ó dá ẹgbẹ́ rẹ̀ àkọ́kọ́ sílẹ̀ ní 1991 ní ìlú Eko lẹ́hìn tí ó ti kii ara rẹ̀ ní fèrè. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Channel O Music Video Awards Best Male video(” Never Far Away”) ni 2006.

Ìlànà àṣà Yorùbá padà mo Ishola lára pé ó ń sàfihàn òwe Yorùbá àti àwọn ọ̀rọ̀ ínú kurani nínú orin rẹ, kò Si lọ irinse orin ilé òkèèrè, láti fi gbé  orin rẹ jáde. Kí asiko ọdún 1950 tó parí ó bere si ni lọ sèkẹ̀rẹ̀ ninu orin rẹ, o si se akale orin ni odun 1960 fún Decca Records, eyi ti o pe akole rẹ ni ” punctuality is the soul of business ”Ni odun 1962 ó ṣe akale LP rẹ akoko.
Olójú méjì ni, orin marun-un lọ sí wa ni oju kọ̀ọ̀kan. Mẹta ninu awon orin náà lápá kan je kìkì àwọn ènìyàn pàtàkì. Ní apá kejì, ní a ti rí àwọn síńgúlù ”Mo sọ pé mo kú àti ” ìkà kò wù wọn”!
Ishola máa ń jókòó tó bá ń ṣeré ni, tí àwọn onílù méjì (lamellaphone), (shakers), agogo, akuba, (claves) àti àwọn elege máa rogba yì í ká. Bákan náà ni ilu agídí gbó, láti fi rán ohun rẹ lowo, (lamellaphone tó ṣòfò (thumb piano), eyi ti o n se iranwo fún ohun.

Ní ọdún 1969, Ishola bere STAR Records Ltd, pelu ajosepo Olórin jùjú, I. K. Dairo. Èyí ni àkọ́kọ́ àkálù orin Afíríkà tí àwọn Olórin rẹ. Ní 1971,o gbé àwo orin rẹ tí ó tà jùlo jáde títí di asiko yii, Oroki social club loni Decca Records, eyi ti o fà ju fọ́nrán milionu márùn-ún lọ.

Abala kan nínú àwọn orin náà ni orin ewì fún egbe àlè pàtàkì kan tí ó gbajugbaja ni ilu Osogbo, níbi tí Ishola ati awon ómo egbe rẹ tí ṣeré fún àwọn oluworan èyí tó máa ń gba wọn tó wákàtí mẹrin sì mẹ́wàá. Ó padà di ọkàn lára àwọn Olórin Nàìjíríà tí ó kókó lọ ṣeré ni òkè òkun, ṣeré ni ile Benin, United Kingdom, Sweden, France, west Germany ati Italy.
Ishola kú ní ọdún 1982 sii ìlú Ìjẹ̀bú igbó. Omo rè musiliu Haruna Ishola náà je olorin, ó sì ń ṣeré, ó sì ń délé de bàbà rẹ. Ó gbé orí tí ó tà gan jáde ní ọdún 2000 tí ó pè akole rẹ ni soyoyo.

Haruna Ishola Bello MON

Olórin ilé Naijiria ni Haruna Ishola je, gbajugbaju sì ni laarin awon olori apala.
Ìlú Nàìjíríà ni ilu Ibadan ni a ti bí à sì mọ ó sì bàbà Olórin apala ni ile Nàìjíríà. Ó máa ń lọ àwọn irinse orin bí agogo, akuba, ìlú, àti bẹẹ bẹẹ lo.
Ọdún 1919 ni wọ́n bi í, ó sì papoda ni odun 1982.
Orin tí Ishola koko gbé jáde ní ọdún 1948, olóògbé ọba Adeoye(orimolusi tí Ìjẹ̀bú igbó), eyi ti o gbe jáde lábé HIS masters voice(HMV) ó baje rárá, ṣùgbọ́n a ìdẹkùn akitiyan rẹ fún un ní orúkọ gege bí í Olórin taye ń fẹ́ laarin awọn otookulu ilé Nàìjíríà. Haruna Ishola bere si ni ṣe akale onka apala ni odun 1955, tí ó fi di ìlú mọ́-ọn-ká Olórin apala, àti ọkàn lára àwọn Olórin tí wọn bọ̀wọ̀ fún ní ilé Nàìjíríà.

Ìlànà àṣà Yorùbá padà mo Ishola lára pé ó ń sàfihàn òwe Yorùbá àti àwọn ọ̀rọ̀ ínú kurani nínú orin rẹ, kò Si lọ irinse orin ilé òkèèrè, láti fi gbé  orin rẹ jáde. Kí asiko ọdún 1950 tó parí ó bere si ni lọ sèkẹ̀rẹ̀ ninu orin rẹ, o si se akale orin ni odun 1960 fún Decca Records, eyi ti o pe akole rẹ ni ” punctuality is the soul of business ”Ni odun 1962 ó ṣe akale LP rẹ akoko.
Olójú méjì ni, orin marun-un lọ sí wa ni oju kọ̀ọ̀kan. Mẹta ninu awon orin náà lápá kan je kìkì àwọn ènìyàn pàtàkì. Ní apá kejì, ní a ti rí àwọn síńgúlù ”Mo sọ pé mo kú àti ” ìkà kò wù wọn”!
Ishola máa ń jókòó tó bá ń ṣeré ni, tí àwọn onílù méjì (lamellaphone), (shakers), agogo, akuba, (claves) àti àwọn elege máa rogba yì í ká. Bákan náà ni ilu agídí gbó, láti fi rán ohun rẹ lowo, (lamellaphone tó ṣòfò (thumb piano), eyi ti o n se iranwo fún ohun.

Ní ọdún 1969, Ishola bere STAR Records Ltd, pelu ajosepo Olórin jùjú, I. K. Dairo. Èyí ni àkọ́kọ́ àkálù orin Afíríkà tí àwọn Olórin rẹ. Ní 1971,o gbé àwo orin rẹ tí ó tà jùlo jáde títí di asiko yii, Oroki social club loni Decca Records, eyi ti o fà ju fọ́nrán milionu márùn-ún lọ.

Abala kan nínú àwọn orin náà ni orin ewì fún egbe àlè pàtàkì kan tí ó gbajugbaja ni ilu Osogbo, níbi tí Ishola ati awon ómo egbe rẹ tí ṣeré fún àwọn oluworan èyí tó máa ń gba wọn tó wákàtí mẹrin sì mẹ́wàá. Ó padà di ọkàn lára àwọn Olórin Nàìjíríà tí ó kókó lọ ṣeré ni òkè òkun, ṣeré ni ile Benin, United Kingdom, Sweden, France, west Germany ati Italy.
Ishola kú ní ọdún 1982 sii ìlú Ìjẹ̀bú igbó. Omo rè musiliu Haruna Ishola náà je olorin, ó sì ń ṣeré, ó sì ń délé de bàbà rẹ. Ó gbé orí tí ó tà gan jáde ní ọdún 2000 tí ó pè akole rẹ ni soyoyo.

Tunde King

A bí Abdul Fatai Babatunde king sì agbegbe àárọ̀ ni àdúgbò olowogbowoni ìlú Èkó ni ọjọ́ kerinle logun oṣù kẹjọ ọdún 1910. Omo Ibrahim sanni King ni, ẹni tí ó jé egbe awon musulumi kékeré ni àdúgbò saro. Baba rẹ jẹ akowe oloye ibile ilé ejò ni ilaro,o si gbe ni fuorah Bay ni Sierra Leone fún igba die. Ó ní agbára tó pò lórí àwọn orin ilé Nàìjíríà.

Ilé ẹ̀kọ́ alakoobeere Methodist abele ni Tunde king, ó sì lọ sí Èkó boys High school. Omo ile eko rẹ kan ló kọ ó bí a ti ń lọ gíta ó sì di olórí egbe ibile kan ” area boys ” tí wọn máa ń Jaye ni mekaniiki ni agbegbe West Balogun.

Ní ọdún 1929 King gbà ṣe àlùfáà ó sì ń sise bákan náà gege bí Olórin àti onigita pelu àwọn irinse mẹta mìíràn. Lára wọn ni gíta, samba, marakaasi, eyi ti o padà yi si tanboríìnì, gita, Banjo àti sèkẹ̀rẹ̀. Ní àárín ọdún 1930 ó gbádùn àwọn anfaani kan tí ó fún ní àṣeyọrí pelu opolopo akale ati igbogunsafefe, sugbon o sì ń ṣe ère ìtàgé láti fi mowo wọlé ní àwọn òde aladaani ni opo ìgbà. Fún àpẹẹrẹ, King ṣeré ni ibi ìsun òkú ẹni pàtàkì, Dókítà Oguntola sapara ni osu kẹfà ọdún 1935.

Pelu ajakale ogún agbaye kejì ni odun 1939, Tunde king darapo mo Mrchant Marines báwọn ọní sowo orí omi). Ó padà sí Èkó ni odun 1941, a ó gburo rẹ bíi ọdún mẹ́kanla tó tele. Won tún ṣe àwárí rẹ nibi tó ti n ṣeré ni pápá Francophone gege bí conakry ah Dakar, Ó sì padà sí Èkó ni odun 1954. Ó kú ní ọdún 1980. Tunde gbé àwọn akaale bíi mélòó kan jáde, Lára wọn ni ” Eko”’ ‘akete” àti alára oto ” ọba oyinbo”(European king)! Owó tá sẹ́ré. Síbẹ̀, àwọn àkọsílẹ̀ náà jẹ́ pàtàkì nínú ìdájọ́ rẹ. Àwọn àkọsílẹ̀ míì ni “Sapara ti sajule orun”, “Dunia (Ameda)” àti “Ojuola lojo agan”. Ní gbogbo, ó ṣe àkọsílẹ̀ ju 30 lọ. Méjì nínú àwọn àkọsílẹ̀ rẹ, “Oba Oyinbo” àti “Dunia” ni wọ́n fi kó sínú CD àkójọpọ̀ Juju Roots: 1930s-1950s, tó jẹ́ ti Rounder Records, ní oṣù kiní ọdún 1985.

Michael Babatunde Olatunji

Olatunji ni a bí sí abúlé Ajido, tó wà nítòsí Badagry, ìpínlẹ̀ Èkó, ní gúúsùwọ̀n Nàìjíríà, ní ọjọ́ keje, oṣù kẹrin, ọdún 1927, ó sì kú ní ọjọ́ kẹfa, oṣù kẹrin, ọdún 2003. Gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ àwọn ènìyàn Ogu, Olatunji ni a sí ìkànsí sí orin àṣà Afriká ní àkókò kékeré. Olatunji dàgbà pẹ̀lú èdè Gun (Ogu/Egun) àti Yorùbá. Ìyá-àgbà rẹ àti ìyá-Ìyá-àgbà rẹ tó jẹ́ àgbàlagbà jẹ́ àwọn olóògbé ti ẹ̀sìn Vodun àti Ogu, wọ́n sì ń bọ́ Kori, òrìṣà  ìbáṣepọ̀.

Nítorí ikú baba rẹ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣẹlẹ̀, láti àkókò kékeré ni wọ́n ti ń mura rẹ sí ipò olóyè. Nígbà tó jẹ́ ọdún mejila, Olatunji mọ̀ pé kò fẹ́ di olóyè. Ó dá àpẹrẹ fún eto ìkànsí Rotary International, ó sì dá a. Àpẹrẹ rẹ ṣèṣeyọrí, ó sì lọ sí Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ní ọdún 1950 láti kópa ní Morehouse College.

Olatunji gba àǹfààní ẹ̀kọ́ Rotary ní ọdún 1950, ó sì kó ẹ̀kọ́ ní Morehouse College ní Atlanta, Georgia. Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ ní Morehouse, ó lọ sí Yunifásítì New York láti kó ẹ̀kọ́ ní ìṣàkóso àjọ. Níbẹ̀ ni ó bẹ̀rẹ̀ ẹgbẹ́ ìkó orin kékeré kan láti rí owó lẹ́gbẹ̀ẹ́ bí ó ti ń tẹ̀síwájú ẹ̀kọ́ rẹ.
Olatunji ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ olorin. Olatunji jẹ́ olokiki fún fífi ọrọ́ àfiyèsí hàn fún ìdájọ́ àwùjọ ṣáájú kí ó tó ṣe àfihàn ní iwájú àwùjọ alãye.
Olatunji jẹ́ olùkọ́ orin, ó sì dá àmọ̀ràn kan ti ẹ̀kọ́ àti ìkọ̀wé àpẹẹrẹ ìkó tí ó pè ní “Gun-Dun, Go-Do, Pa-Ta” gẹ́gẹ́ bí àwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lórí dánmárè. Ó kọ́ àwọn iṣẹ́ dánmárè àti ijó ní gbogbo ọdún láti ìparí ọdún 1950s. Lára ọdún, ó ṣe àfihàn iṣẹ́ ìkó ní gbogbo ilẹ̀ yìí àti kọ́lẹ́jì, yunifásítì, àwọn àjọ ìjọba, àti àwọn àjọ àṣà. Ní ìsàlẹ̀ ni àwọn iṣẹ́ orin rẹ:.

Segun Adewale

Omoba Segun Adewale ni a bí sí ìdílé ọmọ-ọba ní Osogbo, Nàìjíríà ní ọdún 1949. Nítorí pé baba rẹ kọ́ ìmúrasílẹ̀ rẹ nínú orin, Adewale fi ilé silẹ̀, ó sì lọ sí Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà, níbẹ̀ ni ó pàdé àwọn olórin Juju S. L. Atolagbe àti I. K. Dairo. Ní ọdún 1970, Adewale àti Shina Peters jọ ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Prince Adekunle, ẹni tó jẹ́ olùṣàkóso ìtàn Afrobeat Jùjú.

Ní ọdún 1977, Adewale, pẹ̀lú Shina Peters, dá ẹgbẹ́ tuntun kan tó ń jẹ́ Shina Adewale and the Superstars International. Wọ́n ṣe àtẹjáde àkọsílẹ̀ mẹ́sàn-án, ṣùgbọ́n wọ́n pinnu láti pínyà ní ọdún 1980 láti dá ẹgbẹ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan sílẹ̀.

Ní ọdún 1984, orin Adewale ti yipada sí ohun tí a ń pè ní Yo-Pop lónìí.

Francis Awe

Frances Awe jẹ́ ọmọ-ọba ti ìran Yorùbá ní Nàìjíríà. A gbọ́ pé ó jẹ́ amọ̀ja nínú kíkọ orin dùn ún (talking drum) Nàìjíríà. Ìyá rẹ ni ẹni tó ṣe àwárí ẹ̀bùn rẹ nígbà tó jẹ́ ọmọ oṣù méjì péré. Nígbà gbogbo tí ó bá ń kọ́ orin, ó máa ń sunkún. Nítorí náà, ní ọjọ́ kan, ìyá àgbà rẹ pinnu láti mú un lọ sí ibè tí a ti ń kọ́ orin. Francis bá dá ẹkún dúró nígbà tí ó gbọ́ dùndún. Ìyá àgbà rẹ náà ṣe èyí lẹ́mèjì mẹta, nígbà tí ó yá ó darpọ̀ pẹ̀lú àwọn olórin dùndún labúlé, wọ́n sì gbà á lábẹ́ ẹgbẹ́ wọn.

Ní ọdún 1981, Francis gba àkọ́kọ́ ẹ̀kọ́ nínú Dramatic Arts ní Yunifásítì Ife ní ìpínlẹ̀ Osun, Nàìjíríà. Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ, ó rí iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olorin dundun àti Olùrànlọ́wọ́ Àṣà àgbà ní Yunifásítì Lagos, Ilé-Ẹ̀kọ́ Àṣà. Kò pẹ́ tó, ó pinnu pé ó fẹ́ wá sí Amẹ́ríkà kí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ní California Institute of the Arts. Níbè, ó gba àkọ́kọ́ ẹ̀kọ́ nínú World Arts and Cultures.

Ní ọdún 1985, Francis Awe dá ẹgbẹ́ Nigerian Talking Drum Ensemble sílẹ̀ pẹ̀lú iyawo rẹ, Omowale, tó jẹ́ olórin ìjo àtàwọn olórin. Nigerian Talking Drum Ensemble jẹ́ ẹgbẹ́ tó ń ṣe àfihàn pẹ̀lú ìrètí láti kó àwọn ènìyàn mọ̀ nípa àṣà Nàìjíríà nípasẹ̀ orin àti ìjo. Ẹgbẹ́ náà ti rìn àjò lọ sí ibi mẹta ní gbogbo Amẹ́ríkà àti pẹ̀lú Mexico, Italy, Germany, àti India. Pẹ̀lú ẹgbẹ́ náà, Francis máa ń lọ sí yunifásítì àti ilé-ẹ̀kọ́, ó sì tún kọ́ ni àwọn iṣẹ́ àkànṣe. Ó ti kọ orin fún fíìmù, tẹlifísàn, àti lórí pẹpẹ.

Ní báyìí, ó jẹ́ olorin tó ń ṣe àkọsílẹ̀ fún Bindu Records, ó sì ń gbé àwo orin jáde pẹ̀lú dundun rẹ tó ní akọ́lé, Oro Ijinle. Awe ti sọ pé ìpinnu rẹ ni, “Kí n má sọ dundun di irinṣẹ́ àgbáyé nikan, ṣùgbọ́n kí n tún fi ìbáṣepọ̀ ẹbí ti ìyè Afriká kọ́ gbogbo ènìyàn ní gbogbo ilẹ̀ ayé.” Ó sì ní ọmọ méjì.

Salawa Abeni Alidu

Salawa Abeni Alidu ni a bí ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù Karùn-ún, ọdún 1961. Ó jẹ́ ọmọ Ijebu Yoruba láti Ijebu Waterside, nínú ìpínlẹ̀ Ogun. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí olórin nínú waka music nígbà tí ó release àlùfáà rẹ àkọ́kọ́ tó jẹ́ akọ́lé, Late General Murtala Ramat Mohammed, ní ọdún 1976, lórí Leader Records. Àlùfáà yìí di àkọ́kọ́ tó jẹ́ ti obìnrin nínú Yoruba Songs tó ta ju mílíọ̀nù ẹ̀yà lọ ní Nàìjíríà.
Abeni tẹ̀síwájú sí í ṣe àkọ́kọ́ fún Leader títí di ọdún 1986, nígbà tí ó parí ibasepọ̀ pẹ̀lú oníṣòwò àlùfáà náà, Lateef Adepoju. Ó fẹ́ Kollington Ayinla, ó sì darapọ̀ mọ́ ilé-èkó rẹ dipo, tí ó sì wà pẹ̀lú un títí di ọdún 1994.

Ó gba àyẹyẹ “Queen of Waka Music” láti ọ̀dọ̀ Alaafin tó ti kọja ti Oyo, Oba Lamidi Adeyemi ní ọdún 1992. Waka jẹ́ irú orin Yoruba tó ni ìtàn Islam, tó jẹ́ aṣa, tí Batile Alake ṣe àgbékalẹ̀; ó ti pé jù jùjú àti fuji lọ.
Àwọn iṣẹ́ rẹ ni:

  • Late Murtala Muhammed(Leader, 1976)
  • Iba Omode Iba Agba(Leader, 1976)
  • Shooting Stars(Leader, 1977)
  • Ijamba Motor(Leader, 1978)
  • Okiki Kan To Sele/Yinka Esho Esor(Leader, 1979)
  • Orin Tuntun(Leader, 1979)
  • Irohin Mecca(Leader, 1980)
  • Ile Aiye(Leader, 1980)
  • Omi Yale(Leader, 1980)
  • Ija O Dara(Leader, 1981)
  • Ikilo(Leader, 1981)
  • Enie Tori Ele Ku(Leader, 1982)
  • Challenge Cup ’84(Leader, 1983)
  • Adieu Alhaji Haruna Ishola(Leader, 1985)
  • Indian Waka(Kollington, 1986)
  • Ìfẹ́ Dára Púpọ̀(Kollington, 1986)
  • Mo Tun De Bi Mo Se Nde(Kollington, 1986)
  • Awa Lagba(Kollington, 1987)
  • Abode America(Kollington, 1988)
  • Ileya Special(Kollington, 1988)
  • I Love You(Kollington, 1988)
  • We Are The Children(Kollington, 1989)
  • Maradonna(Kollington, 1989)
  • Candle(Kollington, 1990)
  • Experience(Alagbada, 1991)
  • Congratulations(Alagbada, 1991)
  • Cheer Up(Alagbada, 1992)
  • Waka Carnival(Alagbada, 1994)
  • Beware cassette(Sony, 1995)
  • Live In London ’96cassette (Emperor Promotions, 1996)
  • Appreciationcassette (Sony, 1997)
  • With Barrister Evening Of Soundcassette (Zmirage Productions, 1997)
  • Good Morning In America(Alagbada, 1999)

Orlando Owoh (Stephen Oladipupo Olaore Owomeyela)

Orlando Oworh(A bí Stephen Oladipupo olaore Owomeyela:(14/2/1932-4/11/2008) jẹ́ ọmọ orile-ede Nàìjíríà tí ó kọrin tí o si je olori egbe àwọn akọrin tí ó ṣe láti ilé Yorùbá.
Stephen Oladipupo Olaore Owomeyela tí a padà mo sì Oloye, omowe Orlando Oworh wá sí ayé ni ilu Osogbo, Nàìjíríà ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1932 sínú ìdílé Oloye Atanneye Owomeyela àti arábìnrin Christiana Morenike Owomeyela. Ifon ni ìpínlè Ondo ni bàbá rè tí dàgbà, tí ìyà rẹ na si je omo bibi ìlú ọ̀wọ̀.

Baba rẹ jẹ kanlẹ́ kanlẹ́ tí ó sì tún má ń kó orin lèkookan ni ilu Osogbo.

Gégé bí ọmọ ọkùnrin, Owoh se ìṣe kanlẹ́ kanlẹ́ títí di ọdún 1958, ní ìgbà tí wọn gba sínú egbe osere orí ìtàgé, ọmọ orile-ede Nàìjíríà kan Kola Ogunmola láti máa lu ìlù àti kò orin. Oworhse lọ dá egbe akọrin Orlando Oworhse àti àwọn elegbe rẹ sílè ni odun 1960, eyi ti o si sọ irin ajo ogójì ọdún nìdí ìṣe orin rẹ di asiwaju nìdí ìṣe orin pelu egbe orin bí omiman èyí tí ó padà di egbe odò kenneries àti kenneries ẹ adúláwò tí àgbáyé. Oworh je gbajugbaja ni ile Nàìjíríà, kò dá títí di asiko orin ìgbàlódé jùjú àti fuji. Ó ní àwo orin tó lè ní márùn-ún dín-ogota gege bí àṣeyọrí rẹ. Orlando Oworh kú ní ọjọ́ kẹrin, Osu kọkànlá ọdún 2008. Ó wọ kaa ilé lọ ní agege ni Ipinle Eko, Nàìjíríà. Àwọn àwo orin tí ó ti kọ( A kò tò wọ́n ní ṣíṣẹ̀-n-tẹ̀lé)

  • Aiye nyi lo Medley
  • Ajanaku Daraba
  • Apartheid
  • Asotito Aye
  • Awa de
  • Ayo mi sese bere
  • Cain ati Abel
  • Easter special
  • E ku iroju
  • E Get As E Be
  • Emi wa wa lowo re
  • Experience
  • Ganja I
  • Ganja II
  • Ibaje eniyan
  • Igba aye Noah
  • Ire loni
  • I say No
  • Iwa l’Oluwa Nwo
  • Iyawo Olele
  • Jeka sise
  • Kangaroo
  • Kennery de ijo ya
  • Kose mani
  • Late Dele Giwa
  • Logba Logba
  • Ma wo mi roro
  • Message
  • Mo juba agba
  • Money 4 hand back 4 ground
  • Oriki Ojo
  • Orin titun
  • Thanksgiving
  • Which is which

Àwọn orin àdákọ rẹ̀ ni:

  • Brother ye se
  • Day by day
  • Diana
  • Ebe mo be ori mi
  • Zo Muje
  • Egi nado
  • Elese (sinner)
  • Fiba fun Eledumare
  • Ma pa mi l’oruko da
  • Ma sika Ma doro
  • Modupe Medley
  • Oju ni face
  • Okan mi yin Oba orun
  • Olorun Oba da wa lohun Medley
  • Oro loko laya
  • Rex Lawson
  • Wa ba mi jo
  • Yabomisa sawale
  • You be my lover

Èyí tí kò sì tán síbẹ̀.

Sikiru Ololade Ayinde Balogun, MFR

ìtàn ìgbésí ayé Sikiru Ololade Ayinde Balogun,MFR,
Wọ́n bí Ayinde Barrister ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kejì (oṣù ìrèlè) ọdún 1948,sí ìdílé Salawu Balogun, tí ó jẹ́ oníṣòwò, tí ó sì tún jẹ́ alápatà.
Ó lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ní Muslim mission school and the Model school, ní Mushin,Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó padà  kẹ́kọ̀ọ́ nípa títẹ nǹkan (typing) àti ìṣòwò ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yaba polytechnic.

Ayinde Barrister bẹ̀rẹ̀ sí ní  kọrin láti ìgbà èwe rẹ́ wá gẹ́gẹ́ bíi olórin ajíwéré ní ìgbà ọdún Ramadan; ó tẹ̀ síwájú  nípa kí kọrin lóde. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi akọ̀wé fún ilé-isé Nigerian breweries  àti fún Nigerian Army ní  ìgbà ogun abẹ́lé Nàìjíríà. Ó sìn ní ibi ẹgbẹ́ ọmọ ogun kẹwàá tí ìpín kejì ẹgbẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà lábẹ́ ọ̀gágun Adeniran tó sì jagun ní ìlú Awka, Abagana àti onitsha. Ní ìpadà bọ rẹ̀ láti ogun náà, wọn gbé e lọ sí Army signal headquarters, Ní Apapa, wọ́n sì tún padà gbé e lọ sí Army resettlement Center ní Oshodi. Ó padà fi ìṣe ogun jíjà sílẹ̀ lọ gbájúmọ́ ìṣe orin ní kíkọ, tí ó sì ní ẹgbẹ́ orin kíkọ tí ó ní olórin(ọmọ ẹgbẹ́) mẹ́rìndínlógún (34) tí wọ́n pe orúkọ egbẹ́ wọn ní  “Supreme Fuji Commanders”.

Ní ọdún 1966,Ayinde Barrister gbé àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde. Ní ìgbà náà, ó sábà máa ń kọrin pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ ní ibi ayẹyẹ lágbègbè Ebute Mẹta ní Ìpínlẹ̀ Eko fún àwọn oní-ìbárà rẹ̀ tí ó jẹ́ Mùsùlùmí (Muslim). Ó tẹ̀ ṣíwájú nípa gbígbé àwọn oríṣi àwo orin jáde lábẹ́ ilé-isé ìgbórinjáde African songs Ltd kí ó tó bẹ̀rẹ̀ ilé-isé ti ti ẹ̀, “Siky-oluyole Records”. Lára àwọn orin tí ilé-isé ìgbórinjáde   Lp lábẹ́  African songs gbé jáde ni Bisimilahi (1977) àti Ilé ayé dùn pupo/love in Tokyo (Indian sound)(1976). Ní ọdún 1980 síwájú, Ayinde Barrister àti orin Fuji ti di ìtẹ́wọ́gbà fún gbogbo ẹ̀sìn ní ìlú. Ó tẹ̀ ṣíwájú láti ṣe oríṣi àwo orin tí ó fi mọ́ Ìwà (1982), Nigeria (1983), Fuji Garbage (1988) àti New Fuji Garbage (1993) lábẹ́ ilé-isé ìgbórinjáde ti ti ẹ̀. Ó ní àwo orin tí ó gbájúmọ́ tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Reality (2004). Ó ní ìjà pẹ̀lú olórin Fuji mìíràn tí à ń pè ní, Kolington Ayinla ní ọdún 1982.

Ayinde Barrister lọ sí ibi ayẹyẹ ní ìlú London ní ọdún 1990 àti ní ọdún 1993 ní èyí tí ó kọ orin rẹ̀ kan tí à ń pè ní Fuji Garbage.

Orin Fuji rẹ jẹ ọ̀kan lára àwọn oríṣi orin ìbílẹ̀ ti Apala, Sakara, Awurebe, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Pẹ̀lú orin Fuji, Barrister mú orin ìbílẹ̀ Yorùbá ní  ọ̀kúkúndùn ní ìgbà tí ó sì tún ṣe ìfihàn èrè Ìwà réré, ìbọ̀wọ̀ fún àgbà àti ìjàkadì tí ó lòdì sí ayé ọmọ ẹ̀dá. Ó máa ń lo orin rẹ̀ fi dá sí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀/rògbòdìyàn tí ó bá ń ṣẹlẹ̀ ní ìlú,pàápàá òṣèlú. Ó ní ẹ̀bùn kí ó máa fi orin rẹ̀ sọ nnkan mériìírí.

Ọ̀jọ̀gbọ́n Sikiru Ayinde Barrister gba oríṣi àmì-ẹ̀yẹ ní ìgbà ayé rẹ̀, ẹ̀yẹ tí ó lọ́ọ̀rìn tí ó gbà ni jíjẹ́ ọkàn lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ MFR( Member of the Order of the Federal Republic) láti owó Ààrẹ ìgbà náà ní orílè-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2006,Ààrẹ  Olusegun Obasanjo. Àmì ẹ̀yẹ tí ó gbà yí wáyé látàrí àwo orin tí ó fi lé de (kọ) ní ọdún 1995, àwo orin  ọ̀hún ṣàlàyé ní kíkún lórí ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ń dojú kọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí ìlú tí orin ọ̀hún sì tún ṣàlàyé ọ̀nà àbáyọ tí ó ń dojú kọ Nàìjíríà ní ìgbà náà. Ní ọdún 1983, wọ́n fún un ní ẹ̀yẹ PHD orin ní City university tí ìlú Los Angeles.

Èyí ni àwọn orin rẹ̀ :

Ejeka Gbo T’Olorun

  • Vol.1: Waya Rabi
  • Vol.2: Alayinde Ma De O
  • Vol.3: Mecca Special
  • Vol.4: Itan Anobi Rasao
  • Vol.5: E Sa Ma Mi Lengbe
  • Vol.6: Ori Mi Ewo Ninse / Majority Boy(1975)
  • Vol.7: Ile Aiye Dun Pupo / Love in Tokyo (India Sound)(1975)
  • Vol.8: Fuji Exponent(1976)
  • Vol.9
  • Vol. 10(African Songs, 1977)
  • Bisimilai(African Songs, 1977)
  • Omo Nigeria(African Songs, 1977)
  • Olojo Eni Mojuba(Siky Oluyole, 1978)
  • Our Late Artistes(Siky Oluyole, 1978)
  • London Special(Siky Oluyole, 1979)
  • Fuji Reggae Series 2(Siky Oluyole, 1979)
  • Eyo Nbo Anobi(Siky Oluyole, 1979)
  • Awa O Ja(Siky Oluyole, 1979)
  • Fuji Disco(Siky Oluyole, 1980)
  • Oke Agba(Siky Oluyole, 1980)
  • Aiye(Siky Oluyole, 1980)
  • Family Planning(Siky Oluyole, 1981)
  • Suru Baba Iwa(Siky Oluyole, 1981)
  • Ore Lope(Siky Oluyole, 1981)
  • E Sinmi Rascality(Siky Oluyole, 1982)
  • Iwa(Siky Oluyole, 1982)
  • Ise Logun Ise (No More War)(Siky Oluyole, 1982)
  • Eku Odun(Siky Oluyole, 1982)
  • Ijo Olomo(Siky Oluyole, 1983)
  • Nigeria(Siky Oluyole, 1983)
  • Love(Siky Oluyole, 1983)
  • Barry Special(Siky Oluyole, 1983)
  • Military(Siky Oluyole, 1984)
  • Appreciation(Siky Oluyole, 1984)
  • Fuji Vibration 84/85(Siky Oluyole, 1984)
  • Destiny(Siky Oluyole, 1985)
  • Superiority(Siky Oluyole, 1985)
  • Fertiliser(Siky Oluyole, 1985)
  • Okiki(Siky Oluyole, 1986)
  • Inferno(Siky Oluyole, 1996)
  • America Special(Siky Oluyole, 1986)
  • Ile Aye Ogun(Siky Oluyole, 1987)
  • Maturity(Siky Oluyole, 1987)
  • Barry Wonder(Siky Oluyole, 1987)
  • Wonders at 40(Siky Oluyole, 1987)
  • Fuji Garbage(Siky Oluyole, 1988)
  • Fuji Garbage Series II(Siky Oluyole, 1988)
  • Current Affairs(Siky Oluyole, 1989)
  • Fuji Garbage Series III(Siky Oluyole, 1989)
  • Music Extravaganza(Siky Oluyole, 1990)
  • Fuji Waves(Siky Oluyole, 1991)
  • Fantasia Fuji(Siky Oluyole, 1991)
  • Fuji Explosion(Siky Oluyole, 1992)
  • Dimensional Fuji(Siky Oluyole, 1993)
  • New Fuji Garbage(Siky Oluyole, 1993)
  • The Truth(Siky Oluyole, 1994)
  • Precaution(Siky Oluyole, 1995)
  • Olympics Atlanta ’96cassette (Siky Oluyole, 1996)
  • Olympics ’96London Version cassette (Zmirage Productions, 1997)
  • with Queen Salawa Abeni Evening Of Soundcassette (Zmirage Productions, 1997)
  • Barry On Stagecassette (Siky Oluyole, 1997)
  • Democracy(Siky Oluyole, 1999)
  • Mr. Fuji(Barry Black, 1998)
  • “Millennium Stanza” (Fuji Chambers, 2000)
  • “Controversy” (2005)
  • ‘ Reality and Questionnaire ‘ ( 2008).
  • Superiority
  • Fuji Booster
  • Fuji Missile
  • Wisdom and correction
  • Image and Gratitude

Batile tàbí Batili Alake

Batile Alake Batile Alake jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìjẹ̀bú igbó ní ìpìlẹ̀ Ogun. Alhaja Batile Alake kú ní ọdún 2013, ní ọmọ ọdún méjìdínláàádọ́rin. Alake jẹ́ olórin wákà àkọ̀kọ́ tí ṣe orin sínu àwo, ó sọ àwọn olórin mùsùlùmí dì gbajúmọ̀ nípasẹ̀ kíkorin ní ibi ìnáwó káàkiri ilé Yorùbá. Ó jáfáfá ní ọdún 1950s àti 1960s, Ó wà lára àwọn olórin obínrin pàtàkì nínu orin wákà láàárín ọdún 1960 àti 1980. Ara wọn ni  Olawumi Adetoun, Dencency Oladunni, Adebukola Ajao Oru, Foyeke Ajangila Ayoka, Ayinke Elebolo, Aduke Ehinfunjowo, Hairat Isawu, Salawa Abeni àti Adijat Alaraagbo.

Ó máa ń kọrin bíi Ewì tó jẹyọ nínu rara,ọ̀kan lára orin àṣà Yorùbá tí kò wọ́pọ̀, pẹ̀lú àlùjó àti elégbè orin, òun àti àwọn olórin wákà tó kù ṣe àṣeyọrí nípa sísọ ewì kíké di iṣẹ́ orin àti nípa lílo àǹfàní  tí ilé-isé ìgba-orin-sílẹ̀ pèsè. Nígbà tí ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ olórin bíi Salawa Abeni gba oríyìn fún àyípadà orin wákà nípa àlùjó tí o yára, Alake kò tẹ̀tì láti máa tẹ̀síwájú nínu ìlànà rẹ̀.

Ọ̀rọ̀ inú orin rẹ̀ múná dóko nítorí pé ó jẹ́ ẹni tó sún mó àṣà ràrá ju àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ olórin tókù.

Lẹ́hìn tí ó ti di gbajúgbajà ní ọdún 1970, ó kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ orin to jade bíi orin ìyìn, tí ó fi sorí àwọn bàbá ìsàlẹ̀ tàbí ìyá ìsàlẹ̀ tí ó ti sé ní ore rí. Ní 1980 ó yí ìṣẹ rẹ̀ padà nípa lílo àlùjó àmì-ohùn mẹ́ta nítorí àwọn ọ̀dọ́ tí ó ń gbọ́ orin rẹ̀.

Abibu Oluwa

Abibu Oluwa jẹ́ olórin Nàìjíríà tó gbajúmọ̀ fún orin Sakara, ó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí a mọ̀ fú irú orin yìí. Oluwa gbajúmọ̀ ní ìparí ọdún 1920 àti 1930 nígbà tí ó ṣe àwo orin fún Odeon HMV àti Parlphone Record. Àwo orin rẹ̀ pẹ̀lú Odeon jẹ́ ọ̀kan lára orin Yorùbá tí ó wà ní ìgbàsílẹ̀. Ó oríṣiríṣi orin ìyìn fún àwọn gbajúmọ̀ ìlú Èkó ní ìgbà ayé rẹ̀. Àwọn olórin Sakara bíi Yusuf Olatunji àti Lefty Salami jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ orin rẹ̀ Olatunji darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ náà ní ọdún 1920. Àwọn orin tí ó ti kọ ni;

Macaulay Ati Tijani Oluwa, Yoruba (Sakara) and Buraimoh Eku, Yoruba (Sakara). Odeon A 248505

Alli Balogun, Alli Oloko, Yoruba (sakara) and Sanni Adewale, Sakara. Odeon A 248506

Ni Jo Ti AkoAko Daiye, Yoruba (sakara) and Raji Fujah. Odeon A 248507

Orin Eshubayi, Yoruba and Tukuru Ajibabi. Odeon A 248534

Orin Alake Oba Abeokuta and Orin Oshodi. Odeon A 248535